Добавил:
Upload Опубликованный материал нарушает ваши авторские права? Сообщите нам.
Вуз: Предмет: Файл:

YorubaPrimer

.pdf
Скачиваний:
6
Добавлен:
12.02.2015
Размер:
4.28 Mб
Скачать

Õrõ nípa Òýkõwé yìí

Dökítà Adébùsölá Ônäbàjò Ônäyçmí jë Oníÿègùn Akunnilóorun -jí-ni ní Ilé-Ìwòsàn-an Royal Victoria ní ìlúu Bárì, Òýtáríò, Kánádà. Òun sì tún ni olùdarí ilé iÿëç Bis Bus International tí wön þ ÿe àtêjáde êkö ìmõ lórísìírísìí õnà pëlúu Kõýpútà. Òun ni atêwéjade magasínìnnì onígbédègbëyõ Yo: ön , ön . Òun sì ni olùdásílê Çgbë Àjùmõka Yorùbá Ilê Àríwá Amëríkà èyí tí ó wà fún àýfàní àwôn ômô Yorùbá ní ìdálê láti jë kí ó rôrùn fún wôn láti kö èdè àti àÿà ìbílêç wôn.

Ìwé yìí ni àkökö nínú õwö àwôn ìwé tí a ÿe fún àwôn ômô çgbë yìí àti gbogbo àwôn tí ó jç níyàn láti kö èdèe Yorùbá káàkiri àgbáyé. A ÿe téèpù àti àwo kõýpútà tí a mõ sí CD-ROM ní ìbámu pêlú ìwé yìí láti túbõ mú êkö èdè yìí rôrùn fún wôn.

Dökítà Ônäyçmí gbàgbö pé nípa mímú iÿë yìí wáyé, òun ti ÿe êtöô tirê, ó wá yç kí àwôn òbí, aya tàbí ôkô àti àwôn tí ó wà ní ipò láti jë olùkö èdèe Yorùbá fún çlòmìíràn lo iÿë yìí fún ìdàgbàsókè àÿà ìbílêç wa. Alágçmô ti bí ômô rê tán, àìmõö jó kù sí ôwö ômô rê.

Dr. Adebusola Onabajo Onayemi is a specialist Anesthesiologist at the Royal

Victoria Hospital, Barrie, Ontario, Canada. He is also the Executive Director of Bis Bus International, a Yoruba language Multimedia Publishing Company. He is the publisher of Yo: ön , ön . (Know how to Write it , Know

how to Read it ) a bilingual Yoruba/English magazine. He is the founder of Yoruba Readers’ Club of North America which was established to give Yoruba children in the diaspora a practical way to learn their language and culture.

This is the first of a series of books designed for use by members of the club and indeed all who have the desire to learn Yoruba worldwide. There is also a companion tape and CD ROM to facilitate this process.

Dr. Onayemi believes that in doing this work, he is fulfilling an obligation and the completion of the task now rests on the shoulders of parents, spouses and others who find themselves in position to teach Yoruba to use this resource to promote our common heritage.